Pamílẹ́rínayọ̀

Sísọ síta



Ìtumọọ Pamílẹ́rínayọ̀

Cause me to laugh for joy.



Àwọn àlàyé mìíràn

The actual pronunciation of the name is uses an extra ẹ that is omitted in text, i.e. as Pamílẹ́ẹ̀rínayọ̀



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

pa...ní ẹ̀rín-mí-ayọ̀



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

pa...ní ẹ̀rín - to make laugh
mí - me
ayọ̀ - joy, celebration


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Pamílẹ́rín

Olúwapamílẹ́rínayọ̀