Pàímọ́
Sísọ síta
Ìtumọọ Pàímọ́
Keep this (one) safe.
Àwọn àlàyé mìíràn
The name is a prayer to the gods to keep this chid safe from dying. It's a name given to suspected àbíkú children.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
pa-èyí-mọ́
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
pa...mọ́ - keep safeèyí - this (one)
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
IBADAN
Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀
Lérè Pàímọ
famous Yorùbá stage and television actor.