Pàṣẹdà

Sísọ síta



Ìtumọọ Pàṣẹdà

Change authorities.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

pa-àṣẹ-dà



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

pa...dà - change
àṣẹ - authority, command


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL
IJEBU