Pọ̀róyè

Sísọ síta



Ìtumọọ Pọ̀róyè

(The child that comes from) a honourable lineage.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

(ì)pọ̀rí-oyè



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ìpọ̀rí - the chief source
oyè - honour, chieftaincy title


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
OKITIPUPA