Pẹ̀láyọ̀

Sísọ síta



Ìtumọọ Pẹ̀láyọ̀

With joy.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

pẹ̀lú-ayọ̀



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

pẹ̀lú - with, along with
ayọ̀ - joy, happiness


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
AKURE