Oyèyínká
Sísọ síta
Ìtumọọ Oyèyínká
Honor surrounds me.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
oyè-yí-n-ká
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
oyè - chieftaincy title, honoryí - turn
n - me
ká - all around (káàkiri)
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL