Oyèmọ́láwá

Sísọ síta



Ìtumọọ Oyèmọ́láwá

Chieftaincy brought honour (to us).



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

oyè-mú...wá-ọlá



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

oyè - honour, respect, chieftaincy
mú...wá - bring
ọlá - honour, prestige, wealth, nobility


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Mọ́láwá