Oyèlékan

Sísọ síta



Ìtumọọ Oyèlékan

Having this child adds to our rank/honour.



Àwọn àlàyé mìíràn

See also:: Ọlálékan



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

oyè-lé-ọ̀kan



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

oyè - title, honour, chieftaincy
lé - plus
ọkan - one
-


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL
IFE



Irúurú

Lékan