Oyèkọ́rọ̀dé

Sísọ síta



Ìtumọọ Oyèkọ́rọ̀dé

Honour brought wealth/riches.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

oyè-kó...dé-ọrọ̀



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

oyè - honor, chieftaincy ttle
kó...dé - bring
ọrọ̀ - wealth, riches


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Kọ́rọ̀dé