Oyèjọjú

Sísọ síta



Ìtumọọ Oyèjọjú

Chieftaincy is attractive to look at.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

oyè-jọjú



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

oyè - honour, chieftaincy
jọjú - be attractive


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL