Oyèfúnkẹ́
Sísọ síta
Ìtumọọ Oyèfúnkẹ́
Honour gave me (this child) to take care of.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
oyè-fún-n-kẹ́
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
oyè - chieftaincy title, honorfún - for
n - me
kẹ́ - cherish, care for, pet
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL