Oyèdoyin

Sísọ síta



Ìtumọọ Oyèdoyin

Chieftaincy has become sweet.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

oyè-di-oyin



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

oyè - chieftaincy title, honor
di - become
oyin - honey, sweetness


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Doyin