Oyèdiwúrà

Sísọ síta



Ìtumọọ Oyèdiwúrà

Chieftaincy has become (as precious as) gold.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

oyè-di-wúrà



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

oyè - honor, chieftancy
di - become
wúrà - gold


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Diwúrà