Oyèdọlápọ̀

Sísọ síta



Ìtumọọ Oyèdọlápọ̀

Chieftaincy has added honor together.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

oyè-da-ọlá-pọ̀



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

oyè - chieftaincy title, honor
da - pour
ọlá - honour, nobility, wealth, success, prestige
pọ̀ - together


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Dọlápọ̀