Oyèdèjì

Sísọ síta



Ìtumọọ Oyèdèjì

Honor has doubled.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

oyè-di-èjì



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

oyè - chieftaincy title, honor
di - become
èjì - two


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Dèjì