Oyèbádé

Sísọ síta



Ìtumọọ Oyèbádé

A title of honor has met royalty.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

oyè-bá-adé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

oyè - chieftaincy title, honor
- together with
adé - crown, royalty


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Bádé