Oyèmúléró

Sísọ síta



Ìtumọọ Oyèmúléró

Chieftaincy upholds the house.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

oyè-mú...ró-ilé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

oyè - chieftaincy, honour
mú...ró - uphold
ilé - house, home


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Múléró