Owódùnní

Sísọ síta



Ìtumọọ Owódùnní

Money is good to have.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

owó-dùn-ní



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

owó - money
dùn - sweet
ní - have


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL