Otúyalọ

Sísọ síta



Ìtumọọ Otúyalọ

The child of the Òṣùgbó has come to visit us.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

otú-ya-lọ



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

otú - elder of the Òṣùgbó secret society; prominent one
ya - to veer, to steer, to visit
lọ - to go


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
OGUN



Irúurú

Yalọ