Oshógbuyì
Sísọ síta
Ìtumọọ Oshógbuyì
See: Shógbuyì
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ṣó-gba-uyì
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ṣó - sorcerer, fertility god (Òrìṣà Oko)gba - receive, take/take over, fill up, accept
uyì - honor, prestige, nobility
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
OGUN