Oshófowórà

Sísọ síta



Ìtumọọ Oshófowórà

The sorcerer got this child at a high cost.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

oṣó-fi-owó-rà



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

oṣó - sorcerer, òrìṣà oko, the god of fertility
fi - used
owó - money
- buy


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
IJEBU
OGUN



Irúurú

Oṣófowórà

Ṣófowórà

Shófowórà

Fowórà