Orísúnmibáre
Sísọ síta
Ìtumọọ Orísúnmibáre
My head brings me closer to goodness.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
orí-sún-mi-bá-ire
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
orí - head, bodysún - shift, move, expand
mi - mine
bá - meet, join
ire - goodness
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
OGUN