Onítìjú

Sísọ síta



Ìtumọọ Onítìjú

1. The shy one. 2. The self-conscious one.



Àwọn àlàyé mìíràn

A nickname.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

o-ní-ìtìjú



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

o - one who
ní - have, own
ìtìjú - shyness, self-consciousness


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
EKO
OTHERS