Sísọ síta
Auctioneer; One who owns or sells goods (at auction).
oní-gbàǹjo
Ó pọ̀ ní: OYO
Olígbàǹjo
Bóyá o tiẹ̀ ní ìtàn kan láti sọ fún wa nípa orúkọ yìí, tàbí fún wa ní ǹkan tí a ṣì kọ, tàbí fikún oun kan tí a kọ sílẹ̀.