Omíṣọgbọ́n

Sísọ síta



Ìtumọọ Omíṣọgbọ́n

Water (The Ọ̀ṣun river/goddess) makes wisdom.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

omi-ṣe-ọgbọ́n



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

omi - water
ṣe - make, create
ọgbọ́n - wisdom


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
OSUN