Omífúntọ́
Sísọ síta
Ìtumọọ Omífúntọ́
Water gave me (this child) to nurture.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
omi-fún-n-tọ́
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
omi - waterfún - to give to
n - me (mi)
tọ́ - be proper, be on the right path; to have a right to
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL