Olúlẹ́yẹ

Sísọ síta



Ìtumọọ Olúlẹ́yẹ

The lord has honour. The leader/prominent one has honour.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

olú-ní-ẹ̀yẹ



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

olú - Lord, God, prominence, the prominent one
- have
ẹ̀yẹ - honour, regard


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Lẹ́yẹ