Olúdọ̀tun
Sísọ síta
Ìtumọọ Olúdọ̀tun
Prominence is renewed.
Àwọn àlàyé mìíràn
See also: Olú
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
olú-di-ọ̀tun
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
olú - lord, head, prominence, herodì - become
ọ̀tun - new
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL
Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀
Olú Jacobs (Actor)