Olúyínká

Sísọ síta



Ìtumọọ Olúyínká

1. God surrounds me. 2. Prominence surrounds me.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

olú-yí-n-ká



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

olú - lord, God, prominent one
yí...ká - surround
mi - me


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
AKURE



Irúurú

Olúyímiká

Yímiká

Yínká