Olúwatúremijáde

Sísọ síta



Ìtumọọ Olúwatúremijáde

The lord has brought out my goodness.



Àwọn àlàyé mìíràn

This is a modern Christian name, as can be observed from the meaning.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

olúwa-tú-ire-mi-jáde



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

olúwa - lord
tú - unearth
ire - goodness
mi - mine
jáde - go outside


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
IBADAN