Olúwatùmínínú

Sísọ síta



Ìtumọọ Olúwatùmínínú

God has consoled/comforted me.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

olúwa-tù-mí-ní-inú



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

olúwa - lord, God
tù...nínú - console, comfort
mí - me


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Tùmínínú