Olúwatómiwò
Sísọ síta
Ìtumọọ Olúwatómiwò
God is enough for me to look at.
Àwọn àlàyé mìíràn
This name was given to a girl born after four boys.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
olúwa-to-mi-wò
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
olúwa - lord, Godtó - suffice for
mi - me
wò - watch over, look at
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
EKO