Olúwatómiládé

Sísọ síta



Ìtumọọ Olúwatómiládé

Having God is enough coronation.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

olúwa-tó-mi-ní-adé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

olúwa - lord, God
tó - suffice for
mi - me
ní - in, at, for
adé - crown, royalty


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Tómi

Tómiládé