Olúwasúnmisíwájú

Sísọ síta



Ìtumọọ Olúwasúnmisíwájú

God moved me forward.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

olúwa-sún-mi-sí-iwájú



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

olúwa - lord, God
sún - move
mi - me
sí - into
iwájú - forward


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
IBADAN