Olúwapèmísíyè

Sísọ síta



Ìtumọọ Olúwapèmísíyè

God called me to life.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

olúwa-pè-mí-sí-ìyè



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

olúwa - lord, God
pè - call
mí - me
sí - into
ìyè - life


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL