Olúwamúyìwá

Sísọ síta



Ìtumọọ Olúwamúyìwá

God brought this to us.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

olúwa-mú-èyí-wá



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

olúwa - lord
mú...wa - bring
èyí - this (one)


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
OGUN
OTHERS



Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀

  • Múyìwá Ọlárewájú (gospel singer and songwriter) Múyìwá Adémọ́lá (actor

  • filmmaker

  • film producer and director)



Ibi tí a ti lè kà síi



Irúurú

Olúmúyìwá

Múyìwá