Olúwamogbíèlé
Sísọ síta
Ìtumọọ Olúwamogbíèlé
It is God I trust in.
Àwọn àlàyé mìíràn
See also: Fátúgbíyèlé, Fámogbíyèlé
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
olúwa-mo-gbé...lé-iyè
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
olúwa - Lord, Godmo - I
gbé...lé - put on
iyè - wisdom, conscious, mind
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
ILESHA