Olúwalanní

Sísọ síta



Ìtumọọ Olúwalanní

The lord is whom we continue to have.



Àwọn àlàyé mìíràn

See also: Olúwalaní



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

olúwa-ni-a-ń-ní



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

olúwa - lord, God
ni - is
a - we
- continue to
ní - have


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Olúwalaní

Laní

Lanní