Olúwagbèmíníjà

Sísọ síta



Ìtumọọ Olúwagbèmíníjà

God came to my defense.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

olúwa-gbè-mí-ní-ìjà



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

olúwa - lord, God
gbè...níjà - support in a fight, come to one's defense
mí - me


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL
ILESHA



Irúurú

Gbèmíníjà