Olúwafúnkẹ́
Sísọ síta
Ìtumọọ Olúwafúnkẹ́
God gave me (this child) to care for.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
olúwa-fún-n-kẹ́
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
olúwa - God, Lordfún - to give to
n - me
kẹ́ - to take care of, to pamper
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL