Olúwafirepèmí

Sísọ síta



Ìtumọọ Olúwafirepèmí

God called me to/into goodness.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

olúwa-fi-ire-pèmí



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

olúwa - lord, God
fi - use
ire - goodness
pè - call
mí - me


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Firepèmí

Pèmí