Olúwafìfẹ́hànsími

Sísọ síta



Ìtumọọ Olúwafìfẹ́hànsími

God showed me love.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

olúwa-fi-ìfẹ́-hàn-sí-mi



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

olúwa - lord, God
fi - use
ìfẹ́ - love
hàn - show


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL