Olúwadára

Sísọ síta



Ìtumọọ Olúwadára

HOMOGRAPH 1. The lord is good: Olúwadára. 1. The lord does wonders: Olúwadárà



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

olúwa-dára



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

olúwa - lord, God
dára - be good
dárà - create wonders
dá - create
àrà - wonder


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ABEOKUTA



Irúurú

Olúdára

Olúdárà

Dárà

Dára