Olúwadáràdémi
Sísọ síta
Ìtumọọ Olúwadáràdémi
God crowns me with wonders.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
olúwa-dá-àrà-dé-mi
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
olúwa - lord, Goddá - create
àrà - wonder
dé - cover, crown
mi - me
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
OTHERS