Olúwadámisí

Sísọ síta



Ìtumọọ Olúwadámisí

God spared me.



Àwọn àlàyé mìíràn

[See: Dámisí]



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

olúwa-dá-mi-sí



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

olúwa - lord
dá...sí - save, delivered, spare
mi - me


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Dámisí

Ògúndámisí