Olúwadáminí
Sísọ síta
Ìtumọọ Olúwadáminí
God holds my hands.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
olúwa-dá-mi-ní
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
olúwa - lord, Goddá...ní - hold onto
mi - me
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
ILESHA
Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀
Dáminí Ogulu (also known as Burna Boy). Nigerian musician.