Olúwadámísírere
Sísọ síta
Ìtumọọ Olúwadámísírere
God has preserved me for good.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
olúwa-dá-mi-sí-rere
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
olúwa - God, Lorddá - create
mi - me
sí - into
rere - good
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
ABEOKUTA