Olúwabùsúyì
Sísọ síta
Ìtumọọ Olúwabùsúyì
The lord has added to my value.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
olúwa-bù-sí-uyì
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
olúwa - lordbù - add
sí - to
uyì - honour, value (iyì)
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
ILESHA