Olúwaṣoorefúnmi
Sísọ síta
Ìtumọọ Olúwaṣoorefúnmi
God did good things for me.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
olúwa-ṣe-oore-fún-mi
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
olúwa - lord, Godṣe - create
oore - gifts, goodness
fún - for
mi - me
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL