Olúwaṣeunbàbàràláiyémi

Sísọ síta



Ìtumọọ Olúwaṣeunbàbàràláiyémi

The lord has done great things in my life/God has done extremely great things for me.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

olúwa-ṣeun-bàbàrà-ní-ayé-mi



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

olúwa - lord, God
ṣeun - did a good thing
bàbàrà - big, great
ní - in
ayé - life, world
mi - mine


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL